text stringlengths 1 44.6M |
|---|
Fún ìdí èyí, kò yẹ kí ilé náà di àdàwólulẹ̀. |
Ẹ ṣeun. |
Ó nírú ẹni tí àwọn olùgbọ́ọ wa máa ń nífẹ̀ẹ́ sí. |
Ìloro àbáwọlé ìwọ̀-oòrùn-un ààfin náà nìkan ló ṣì ń dúró. |
A sọ ibi tí yóò ti bẹ̀rẹ̀ ìwalẹ̀, ìgbà tí yó bẹ̀rẹ̀ àti bí yóò ṣe bẹ̀rẹ̀ . |
Ìyá náà kò fara mọ́ ìbáṣepò ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú ọmọbìnrin tí ó wá láti ẹ̀yà mìí ràn yìí, ọmọbìnrin tí ó dá ṣáṣá tó sì já fáfá - bí i ẹnu abẹ́rẹ́; ọmọbìnrin ẹlẹ́jọ wẹ́wẹ́ yìí; tí ó kàwé gan-an tí ìgbéraga sì ti gùn. |
Àmọ́ ṣá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ti kọ̀yìn síjọba lórí ìgbésẹ̀ yìí. |
A kì í kórìíra ọ̀fọ́n-ọ̀n ká finá bọ ahéré. |
Ilé ẹjọ́ ìbílẹ̀ kọ ìwé ẹ̀dùn tí Min Htin Ko Ko Gyi kọ fún béèlì. Ìgbẹ́jọ́ọ rẹ̀ tún di ọjọ́ 9, oṣù Èbìbì ọdún-un 2019. |
Bà bà bà ...bàbá...bababa...', Tinú ń sọ̀rọ̀ wẹ́wẹ́, Ó ti wá lè dá dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀ tín-ín-rín-tín méjì yẹn láìsí ìrànwọ́. Ó ń dúró pé kí bàbá kì í kú orí ire, kí ó tó di wí pé ó tẹ̀síwájú láti jẹ́ isẹ́ kan – iṣẹ́ yẹn! |
Ṣùgbọ́n tí a ò bá gbé ìgbésẹ̀ nísinyìí, ká sì jọ ṣiṣẹ́ papọ̀, a máa nílò láti ṣínà fún bílíọ́nù kan ènìyàn kí ọ̀rún ọdún yìí tó parí. |
Abala 1c sọ bí ìwé àbádòfin náà yóò ṣe "mú, ṣàkóso àti fi ààbò bo ìlònílòkulò àwọn ìṣàmúlò àti ẹ̀rọ adánìkanṣiṣẹ́ orí ẹ̀rọ ayélujára". |
Ó rántí pé ó ti sọ nǹkan tí ó jọ èyí ní ìgbàtí órí iyẹn. |
Iléeṣẹ́ náà gbọdọ̀ lo èrè tí wọ́n bá rí fi tún àwọn odòo wa ṣe àti ṣíṣe àbójútó ẹ̀mí ọmọ ènìyàn. |
Nílé, Làbákẹ́ pariwo, Jáde! Jáde! Àlàmú! |
Èyí ṣàjèjì, Ọkàn ọ̀fintótó àwọn ará àdúgbò wọ́n wà lókè, ní àwọn ọjọ́ mìíràn, àwọn aládùúgbò yìí máa ń tẹ́tí sí bí Àlàmú ṣé ń ṣáná sí ẹ́ńjíìnì ọkọ̀ jalopí rẹ̀ – tí ó fi ń dà wọ́n láàmú. |
Ní alẹ́ àná, ó rántí pé òun kí ọkọ òun pé “ó dàárò” kí ó tó lọ sùn. Àlàmú sì kanrí mọ́lẹ̀ ní ìdáhùn tí ó sì gbọ́ dídún bí ó ṣe ń ti ilẹ̀kùn nígbàtí ó ṣe díẹ̀, nígbà tó sì yá, ohùn híhanrun rẹ̀ ló ń gbọ́. |
Ìdàgbà sókè tuntun kan ló dé, wọn yóò sì ní láti sún ọjọ́ ẹrù kíkó síwájú. |
Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ owó ńlá mi ni. |
Etí lobìnrín fi ń gbọ́ ohùn orò. |
Ìbéèrè kan tí ó nílò ìdáhùn ni ti ọ̀nà ìtànkálẹ̀ àrùn yìí: bóyá ó leè rànká láti ara èèyàn kan sí ìkejì, àti ìyè èèyàn mélòó ló leè kó àìsàn yìí látara ẹni tí ó bá ti ní i. |
Òwìwí náà ta kété. Agbẹnusọ Ìgbìmọ̀, Job Ndugai, gbìyànjú láti yí ìgbàgbọ́ ìbílẹ̀ padà pẹ̀lú àlàyé tí ó ní iyè nínú: |
Wọ́n yà á sọ́tọ̀ ní ESUTH Colliery Parklane, wọ́n sì fi àyẹ̀wọ̀ tí wọ́n ṣe fun un ṣọwọ́ sí àjọ NCDC ní ọjọ́ 14, oṣù Ẹrẹ́na fún àyẹ̀wò. |
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Mother's Savings Club, Nàìjíríà. I'm Àwòrán láti ọwọ́ Karen Kasmauski / USAID ní Ilẹ̀-Adúláwọ̀ ní orí United States government work, public domain. |
Ìwé tí a kọ ránṣẹ́ sí gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ìrántí àwọn ìpinnu kíkọ́ alífábẹ́ẹ̀tì tuntun náà tí kò tíì wá sí ìmúṣẹ. |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọn ò tíì kẹ́kọ̀ọ́ jáde tí wọ́n fi agbára àkàndá ènìyàn hàn nípasẹ̀ iṣẹ́ takun-takun àti ìfọkànsin wọn. |
Nítorí pé a kò ní eléré mìíràn tí ó ti ṣe àmúlò àṣà wa tó báyìí ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn. |
Ṣùgbọ́n ǹkan rere kan tó jáde lati ibi àjálù burúkú yìí ni àkíyèsí tí ìtàn yìí múwá nípa ẹ̀hónú àwọn ẹranko igbó tí wọ́n wà nínú ewu. |
A kì í yàgò fún ẹlẹ́ṣin àná. |
Ipò tí Àlàmú wà á máa yàtọ̀ sí dáadáa láti ìsínyì lọ. |
Ní ìṣẹ́jú kan, ó ṣàkíyèsí ibi tí ó wà. Kíá ó bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀ ó sì gbé ẹrù rẹ̀ kékeré sọ́wọ́ gírígírí: |
Àjàfúnẹ̀tọ́ ìkẹ́gbẹ́ Mauro Brito sọ ní tirẹ̀ wípé obìrin gbọ́dọ̀ ní ìgbéraga "nígbàtí [wọ́n] bá jẹ́ aṣojú nínú iṣẹ́ gbogbo": |
Síbẹ̀, ẹ fi ojú inú wò ó díẹ̀ si, ẹ ó sì ri wí pé ìpinnu mẹ́tàlá nínu mẹ́tà-dín-lógún ò lè di ṣíṣe àyàfi tí àtúntò tó lágbára bá débá ilé-iṣẹ́ kùkúyè. |
Sísọnù sínú ògbufọ̀: Ìdí tí Atúmọ̀ Google ṣe ń kùnà — nínú títúmọ̀ èdè Yorùbá — àti àwọn èdè mìíràn |
Ó wá bẹ̀rẹ̀ sí ní di ẹ̀rù fún Olóyè Ògúntósìn — ó ń rẹ̀ ẹ́ látinú wá, ó wí fún Ohùn Àgbáyé. |
Èmi àti akẹgbẹ́ mi Dr. Mary Anne Franks ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn aṣòfin orílẹ̀-ède US láti ṣe òfin tí yóò fòfin de ayédèrú ènìyan díjítà tó léwu tó dọ́gba pẹ̀lú jíjí ìdánimọ̀. |
Kàkà kí o gba àfilé odù ààbò, o lè yan iṣẹ́ ìfẹ̀rílàdí tàbí ẹ̀rọ iṣẹ́-àìrídìmú àládàádúró. |
Òfin Ẹ̀tọ́ Ààbò Abódiakọ-akọ́diabo Ènìyàn ọdún 2018 tí a bu ọwọ́ lù nínú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin fi àṣẹ fún ọmọ ẹgbẹ́ náà láti gba ìwé àṣẹ ọkọ̀ wíwà, ìwé ìrìnnà, ní ẹ̀tọ́ láti pààrọ ìṣẹ̀dá ẹni nínú àkọsílẹ̀ ìlú àti Àjọ Ìforúkọsílẹ̀ (NADRA), ìfòpinsí ìjìyà, àyè láti kàwé, iṣẹ́ nínú káràkátà àti ètò ìlera láì sí ìyàsọ́tọ̀. |
Báyìí ní ti ọ̀rọ yìí, àwọn ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ wọ́n ṣíwájú kí Celtel tó sọ wọ́n di èyí tí ò ga ju ara lọ. |
Ṣùgbọ́n oríire mi, mi ò ní láti ṣe èyí fún ìgbà pípẹ́. |
Àkọ́kọ́, láti dèna àkóràn ìyá-sí-ọmọ. |
A gbìyànjú láti ní òye... O gbọ́dọ̀ yé e. |
Mo ronú nípa àwọn ìgbà tí mo wà ní ilé-ẹ̀kọ́ èwe ní orílẹ̀-ède Zimbabwe àti àwọn ọmọ tókù tí a jọ wà ní ilé-ẹ̀kọ́. |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, owó oṣù tí ó kéré jù lọ nínú tó HK$16,800 (US$2,200) dollars. |
" Àwọn wá rèé, gbogbo wọn lápapọ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n lè sọ ìrírí yìí fún ìgbà àkọ́kọ́ àti láti ṣe àtilẹyìn fún ara wọn fún ìgbà àkọ́kọ́. |
Ọ̀kan ní: |
Muhammad Buhari, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Creative Commons. |
Ń pèsè ìwífún-alálàyé ọ̀nà jínjìn |
Kìí ṣe wí pé a lè gba ayédèrú gbọ́ nìkan, a lè bẹ̀rẹ̀ sí sọ ìgbàgbọ́ nù nínu òtítọ́. |
Ó rò pé, Beijing ló yẹ á bá wí. |
Àwọn alágbàwí èdè gbà wí pé lílo ìlànà Látíìnì, tí ó jẹ́ ìṣọwọ́kọ láti ilẹ̀ òkèèrè, fún kíkọ àwọn èdè Ilẹ̀-Adúláwọ̀ sílẹ̀, fi ilẹ̀ náà sínú ipò ẹrú. |
Ìtúmọ̀ Ìtúnwí-ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan-an |
O gbọdọ̀ ti gbààyè alábòójútó àràmàndà láti wo ojú-ewé yìí |
Orí Àlàmú wà lókè. |
Níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kan, a bi àwọn èwe tí ó kópa: |
Ní kété tí iṣẹ́ẹ VPN bá ti wà, o lè lò ó fi wọ ojú ìwé ìtàkùn-àgbáyé, ímeelì, iṣẹ́-ìjẹ́ oníwàràǹṣesà VoIP, àti iṣẹ́ orí ẹ̀rọ ayélujára tó kù. |
Ó jókòó ní ilé-ìjẹun pẹ̀lú ọ̀rẹ rẹ̀ kan nígbà tí ó kọ́kọ́ rí i: fọ́rán oníṣẹ́jú méjì àti ogún ìṣẹ́jú ààyá ara rẹ̀ tó ń ní ìbálópò. |
Ìfẹ̀hónúhàn ní Luanda (ọjọ́ kẹrin oṣù Èrèlé). |
Asọ̀ tí ó wáyé láìpẹ́ yìí láàárín Ààrẹ àná, Olúsẹ́gun Ọbásanjọ́ àti Ààrẹ tí ó wà lórí àlééfà, Ààrẹ Muhammadu Buhari – tí àwọn méjèèjì jẹ́ ajagun fẹ̀yìntì afipásèjọba ológun –ní ipa tí ó pọ̀ lórí ètò ìdìbò oṣù tí ó ń bọ̀. |
Àbúrò kì í pa ẹ̀gbọ́n nítàn. |
Syed Noman ni ó ní àwòrán. |
Ìdájọ́ tí a fún wọn tó ọdún 15 nínú ẹ̀wọ̀n. |
Wón ti ṣe àkọsílè ẹjọ́ rẹ̀, ọ̀nà àti ṣiṣẹ́ rẹ̀ sì ti jáde. |
Ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ Ààrẹ Ilham Aliyev àti amóhùnmáwòran REAL TV ní Oṣù Èrèlé 12. |
bí àpẹẹrẹ Ìṣàsopọ̀ ilé |
Inúu mi dùn nítorí wípé à ń gbé ọ̀ràn ohun tí ojú àwọn ọmọ-adúláwọ̀ máa ń rí ní wọ́n bá béèrè fún ìwé ìrìnnà wọ Orílẹ̀-èdè òyìnbó àti ohun ti ó tan mọ́ ọn yè wò. |
Bí adojúkọ bá dojúkọ ẹ̀rọ ayárabíàṣáà rẹ tàbí ẹ̀rọọ̀ rẹ, tí iṣẹ́-àìrídìmú alamí wà lóríi rẹ̀, iṣẹ́-àìrídìmú alamí lè máa wò ọ́ bí o bá ń tẹ ọ̀rọ̀-ìfiwọlé olúwaà rẹ. |
A rán Wa Lone àti Kyaw Soe Oo sí ẹ̀wọ̀n ọdún méje fún rírú òfin Ìkọ̀kọ̀ sáà-akónilẹ́rú. |
Ṣùgbọ́n kété tí ó pé ọdún méjì lẹ́yìn ti Àlàmú dé, ìbànújẹ́ tí ó gbọ̀nà àràmìíràn yọ ló tún dé bá Màmá. |
Ó hùn mí láti mọ IBI tí wọ́n ti ṣe ìwádìí-àyẹ̀wò yìí ní Nàìjíríà. |
Kò sí èdè yìí lorí Kolibri |
Bí omi-dídì ilé ayé ṣe ń yọ́, òkun ń kún. |
Ó yán, ara kò rọ̀ ọ́rárá, apá rẹ̀ yi, òòyì ń kọ́ ojú rẹ̀. Ó ń ṣe é bí i ti ìyàwó ilé tí ógún iyán ẹ̀kún odó márùn-ún lánàá fún àwọn àlejò aláfòruwọ̀lú. |
Ẹ̀wẹ̀wẹ̀ ìwífún rẹ lè jẹ́ lílò fún àwọn akèdè-iṣẹ́-àìrídìmú ti Kolibri tí yóò sì jẹ́ pínpín fún àwọn aṣèdá ọgbọ́n àtinudá láti mú kí iṣẹ́-àìrídìmú àti àwọn ohun àmúlò fún onírúurú ohun tí irúfẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fẹ́ ó gbé pẹ́lí sí i |
"Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ti kọ̀yìn síjọba lórí ìgbésẹ̀ yìí" |
Fi ààyè gba ẹnikẹ́ni láti ṣẹ̀dá ìṣàmúlò akẹ́kọ̀ọ́ tiwọn? |
Níparí, ìwádìí ti fi hàn wípé àwọn òǹlò kan máa ń yan ọ̀rọ̀-ìfiwọlé tí kò nípọn tó bí wọ́n bá f'ààyègba 2FA tán, pẹ̀lú èrò wípé ọ̀nà kejì yóò dáàbò bò wọ́n. |
Ohun tí a nílò láti ọ̀dọ̀ọ yín ní fún un yín láti lóye wípé iṣẹ́ àtinudá ni epo rọ̀bì tí ọpọ́n sún kàn tí ó sì yẹ kí a bu ìyìn fún iléeṣẹ́ náà. |
Òwìwí kan kọ̀ kò kúrò nínú ilé ìgbìmọ̀ ìjọba Tanzania. Àmìi kí ni èyí? |
Bákan náà ni wọ́n máa ń gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkàn tí ó máa ń dànù káàkiri ilẹ̀, a sì mọ́ wípé oúnjẹ yẹn kì í ṣe ojúlówó, tí àtọwọ́dá ni. |
Ilé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ orin kíkọ kan ṣoṣo ní Zanzibar ti fẹ́ di títì pa |
“Ó yé mi bí o ṣe ń ṣe yín màdáámú. |
Làbákẹ́ béèrè, ó dạ́tọ́ mì. |
“Gbà mí, gbà mí!” ò yẹ àgbà; àgbà kì í ṣe ohun àlémú. |
Láti rán wa léti pé kódà nílẹ̀ Adúláwọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè kan ń bẹ ti a kò mọ̀ wí pé wọ́n wà: [#tíIlẹ̀Adúláwọ̀bájẹ́iléọtí orílẹ̀-ède Lesotho yóò jẹ́ ẹni náà tí ẹnikẹ́ni ò fi bẹ́ẹ̀ mọ̀ ṣùgbọ́n tó máa ń wà nínú àwòrán ní gbogbo ìgbà. |
Àwọn àyípadà kò di àpamọ́ |
Nítorí tìrẹ. Mo ti rubo àwọn òrìsà pẹ̀lú ewúrẹ́, orógbó, ataare àti epo pupa. |
Ní báyìí, òṣèlú ìṣọ̀kan ilẹ̀ Adúláwò ti wà tẹ́lẹ̀, nítorí náà mi ò ṣe àgbélẹ̀rọ ǹkan tuntun níbí. |
Nǹkan tí Àdìó ń sọ ń ṣiṣé àmúmọ́lẹ̀. |
Pẹ̀lu pé wọ́n ń gbé ní orílẹ̀-ède tó rẹwà, tó rọrọ̀, pẹ̀lú ànfàní sí àwọn òògùn tó lágbára jù, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ wí pé ìkànkan gbogbo àwọn aláìsàn mi ni wọ́n kú tán. |
Ní ọ̀rọ̀ọ Prem Chand: |
Bí mo bá ra irun aláwọ̀sórí, Olúwa ò! Dàpọ̀ náàá fẹ́ fìlà”. |
Mílíọ́nù kan lé ẹgbẹ̀rún lọ́nà erínwó ni àwọn aláboyún ní àwọn orílẹ̀-èdè tí ìpawó-wọlé wọn kére tàbí tó wà lágbede méjì tí wọ́n ń gbé pẹ̀lu kòkòro apa sójà ara nínú àwọn wọ̀nyí, ìdá àdọ́rùn wà ní iwọ̀-oòrun ilẹ̀ Adúláwọ̀. |
Èyí ni àbùdá àhámọ́ Èṣùníyì kan. |
Mo ni, "báyìí, ṣé ò ń sọ fúnmi wí pé mò ń dókówò nínu kùkúyè lọ́wọ́lọ́wọ́ yìí? |
Màmá fúnrarẹ̀ á lé e mú. |
Ọdún mẹ́fà sẹ́yìn, ní ọjọ́ 15, Oṣù Igbe ọdún 2014, ó tó 200 àwọn ọmọdébìnrin tí ọjọ́ orí wọn ò ju ọdún 15 àti 18 lọ, láti iléèwé Gíga Ìjọba Obìnrin ní Chibok ẹ̀bà Maidiguri, ní àríwá-ìlà-oòrùn Nàìjíríà ni ẹgbẹ́ afẹ̀míṣòfò èlẹ́sìn Mùsùlùmí Boko Haram sọ di ẹni tí a fi túláàsì mú sí ìgbẹ̀sìn. |
Àwọn ẹgbẹ́ iléeṣẹ́ oníròyìn àti ajà-fún-ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ń ṣe àjọyọ̀ọ ti ìdásílẹ̀ lẹ́wọ̀n-ọn akọ̀ròyìn Reuters Wa Lone àti Kyaw Soe Oo tí ó lò ju ọjọ́ 500 ní àtìmọ́lé fún ipa tí wọ́n kó nínú ìwádìí òfíntótó ìṣẹ̀lẹ̀ ìpanípakúpa àwọn olùgbée Rohingya kan ní gúúsù Myanmar. |
Làbákẹ́ létí, ó sì tẹ́tí sí àwọn ará àdúgbò wọn yìí. |
Ìtúmọ̀ Ìtúnwí-ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan-an |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.